Publisher's Synopsis
Awọn itan Bibeli ti inu iwe yi yio jẹ iranwọ fun awọn ọmọde lati mọ pe (ranti pe) ohunkohun yo wu ti nsẹlẹ ninu aiye wọn tabi ni ayika wọn, Ọlọrun ntọju, bẹni O si nsọ wọn lọsan ati loru. Ko dabi awọn obi wa, Ọlọrun ki i sun tabi ko sarẹ. Ọlọrun si mọ ọjọ waju. O jẹ olododo ati Ẹniti npa adehun Rẹ mọ.